Yoruba

Ajọ ton rí soro dúkìá bẹ̀rẹ̀ sini ṣe àyẹ̀wò ikede Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́

Níbamu àjọ ton rí soro kikede dúkìá ẹni, tí bẹ̀rẹ̀ sini ṣe àyẹ̀wò dúkìá oni bilionu mejidinlaadota náírà èyí tí Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, onímò ero Seyi Makinde kéde rè losu kẹfà ọdún yìí.

Olùdarí àjọ náà ńipinle Ọ̀yọ́, Ogbeni Bisi Atolagbe ló sísọ lójú ọ̀rọ̀ yìí nilu Ìbàdàn, lákòókò ìpàdé àwọn adarí àjọ náà fẹ́ kún iwoorun gusu pẹ̀lú ọmọ ẹgbẹ́ ton ṣojú ẹkùn àjọ náà nínú ìgbìmò CCB, Ojogbon Samuel Ogunda rẹ.

Ojogbon Atolagbe sọ pé, òun ti fi isiro iye dúkìá náà sowo sì olulese àjọ òhun tó wà nilu Abuja, teto ayẹwo náà sì ti bẹ̀rẹ̀ lèyẹ osoka.

Kò sai tókasi pé, ó ṣe ṣe kí ètò náà fale ranpe nítorí àwọn abala kan nínú ètò ayẹwo náà tó lọ́wọ́ ìmò ẹ̀rọ nínú tó sí ṣèlérí wípé ní kété tayewo òhun bá parí niwọn yóò kéde rè síta.

Adebisu/Ogunkola.

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *