Yoruba

Ijoba Ipinle Oyo Fofin Gbe Adota Oko Lori Diduro Lona Aito

Ninu iyanju ati se afomo igbokegbodo oko lawon opopona masose nipinle Oyo keto irina le jagaara, Ajo ti o nse amojuto igbokegbodo oko nipinle Oyo (OYRTMA) ti fofin gbe oko to to adota lopopona to lo si iwo lagbegbe opopona masose Ibadan silu Eko nilu Ibadan.

Opo oko akeru ni won duro lailobikan lawon opopona naa leyi to se okunfa sunkere gbakere oko pelu bo se pagina igbokegbodo.Awon oko elejo naa ni won wo lo solu ilese Ajo naa to wa Lagodi keto irina le ja gaara.

Nigba toun baa awon awako ti won fi ofin gbe oko won soro, Alaga Ajo OYRTMA, Omowe Akin Fagbemi, to saaju awon iko ajo naa salaye pe, ijoba to wa lode nipinle Oyo koni faye gba fifi aye ni enikeni lara, sugbon titele ofin lati fa oju awon oludokowo ile okere mora nipase ayika to rorun fun igbokegbodo oko.

Oluwayemisi Dada

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *