Sise iwode odun kan tiwon fehonunhan lati fopin si iko SARS ti n lo lowo bayii lawon apa ibikan ni ile yii, eto ifehonunhan naa lo n waye nilu Ibadan, Akure, Eko, Abuja, ati awon ibomi naa.

Ni ilu Ibadan ti s’oluulu ipinle Oyo l’awon olufehonuhan naa ti gunle yiyi gbogbo igboro ka, bere l’atagbegbe Iwo Road lo s’awon apa agbegbe toku ninu eyi tatiri Mokola losi olulese ijoba toku, akoroyin ile ise, Radio Nigeria jabe pe, oun r’awon ajo alaabo lawon ibi to se koko n’ilu Ibadan, lati dena igbese tite oju ofin ati ilana mole, bee si leto kata kara nlo nibamu pelu ofin laisi wahala kankan.

Niti, agbegbe Lekki Toll Gate ni ilu Eko, l’awon oko naa tinto lo lenu ifehounhan fifo pinsi iko SARS.

Awon ajafeto omoniyan ti won gbe awon oko won sita fun ifehonuhan ohun ni won so asia orilede yii mo ara oko won to si n fe lelele pelu kiko awon orin ifehounhan lolokan ojo kan.

Won so pe, awon yoo ma lo yika tibu-toro enu iloro Toll Gate Lekki ohun, l’ona lati fi ehonu awon han lati fo pin si iko SARS.

Bakana, ifehohuhan lati sammi iranti fifonpinsipinsi iko SARS, iru e ti bere ni gbagede ile-ile eka eto idajo lagbegbe Maitama nilu Abuja.

Awon olufehounhan naa ti wan akole lowo topo ninu won si wo aso alawodudu.

Bee si lawon ajo alaabo naa duro wamuwamu nibudo naa, lati fese ofin ati ilana mule ati didari awon olufehonuhan naa ti gba apa kan loju popo ohun.

A o ranti pe, lojo kankanla osu kewa odun 2020, Aare Muhammadu Buhari tu iko SARS ka, nibamu pelu bawon eeyan awujo se ke gbajare ati ifehonuhan to gbawon fodidi ojo maarun gbako, ko to dipe, won tu iko alabo SWAT ropo won.

NET/Folakemi Wojuade

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *