Yoruba

Ijoba Apapo Ngbero Owo Iranwo Fun Awon To Ku Die Kato Fun Lawujo

Ijoba apapo ngba lero lati bere sini fun awon to ku die kato fun lawujo ni owo iranwo to kuro lori epo ti yo si je fifun won ni egberun marun losoosu.

Igbese yi ni won yo se fun odun kan atabo, pelu bi ijoba sen gba lero lati fopin si owo iranwo lori epo nigbati yo ba fi di arin odun 2022.

Alakoso fun eto isuna ati atoo gbogbo, Hajia Zainab Ahmed lo siso loju oro, yi nilu Abuja, to si so pea won eeyan laarin ogbon si ogoji million ti ko ri tajese nile yi, ni yo janfani re.

O se lalaye pe iye awon eeyan yo janfani re, lawon yo mo, pelu owo to ea nle leyin ti won ba ti yo owo iranwo lori epo tan.

Aminat Ajibike/Ololade Afonja

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *