News Yoruba

Ijoba Ipinle Ogun Lohun Yoo Samulo Eka-Ere-Idaraya Gegebi Ohun Elo Irolagbara Fawon Odo

Ijoba ipinle Ogun ti fowo ipinu re soya lotun pe, ohun yoo samulo ere idaraya gege bi eroja lati seto agbega eto irolagbara ohun igbese lati gba awon odo lowo iwa odaran yoowu.

Alakoso foro iroyin ati atoo gbogbo, Alhaji Waheed Odusile so eyi lasiko to nside ose eto awon akoroyin ere idaraya SWAN todun 2021, nilu Abeokuta.

Alhaji Odusile, enito fanrere Pataki ere-idaraya fun idagbasoke awujo nii idagbasoke eto ere idaraya kii se ojuse ijoba nikan amo ojuse gbogbogbo.

Alakoso foro iroyin titun se alaga eto ohun, nii ose Pataki fawon akoroyin ere-idaraya lati gunle awon eto ti yoo seranwo nidi mimu agbega baa won to nkopa ninu ere idaraya.

Saaju, alaga egbe awon akoroyin ere-idaraya nile yii, eka tipinle Ogun, Alhaji Hakeem Akintunde ti tokasi pe, agbekale ofin tooye yoo mu kawon odo lee kopa ninu ere idaraya lai fooya.

Folarin/Idogbe

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *