News Yoruba

Adari Tele Lorilede Nigeria, Ernest Shonekan Tije Olorun-N Pe

Olori orilede yii tele, lakoko isejoba fidehe, oloye Ernest Shonekan, enito gba eti akoso lowo ogagun ibrahim babagida tije olorun nipe.

Oloye Shonekan je olorun nipe nilu eko leni odin marundinladorun, o je alaga isejoba fidihe larin ojo kerindinlogbon osun kejo si ojo ketadinlogun osun kokanla odun 1993 nigbati ologbe ogagun sanni –abacha to dipo akowe leto abo mu dite gbajoba lowo re.

Net/Idogbe

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *