Home Posts tagged Ijoba Ipinle Ogun
Yoruba

Ìjọba ìpínlẹ̀ Ògùn sèlérí láti fìyàjẹ akẹ́kọ́ọ̀ yóòwu tó bá hùwà àitọ́ láwọn ilé-ìwé

Ìjọba  ìpínlẹ̀ Ògùn ti kéde pé, wọn yóò lé èyíkèyí àwọn akẹ́kọọ tó bá domi àláfìa ìkẹ́kọ́ọ̀ rú, láwọn ilé-ìwé gbogbo tó ń bẹ nípinlẹ̀ náà kúrò nílè wé. Alákoso fétò ẹ̀kọ́ ìmọ̀ sáyẹ̀nsì àtìmọ̀ ẹ́rọ nípinlẹ̀ Ògùn, ọ̀jọ̀gbọ́n Abayọmi Arigbabu ló sísọ lójú ọ̀rs yíì nílu Abẹokuta lákokò tón báwọn oníròyìn sọ̀rọ̀ lórí báwọn […]Continue Reading