Yoruba

Àjọ W.H.O. f’amonran síta lórí ìtànkalẹ Kokoro Covid-19

Àjọ eleto ìlera lagbaye, WHO s’ọpe àwọn owó ta ń ná nílè yíì leè mú ki atankale kokoro Coronavirus rugogo si. 

Nitori naa won pe fun iduna-dura èyítí kise atowodowo owó. 

Bakana wọ́n tún fìdí rẹ múlẹ̀ pé ó ṣe pàtàkì kí àṣà owó fifo lẹ́yìn dídi owó mú jẹ́ oun tí a gbodo mú lókunkúndùn. 

Nítorípé kòkòrò yí leè lè mọ nkan fún òpó ọjọ. 

Yẹmisi Dada/Kẹmi Ogunkọla

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *