Awon awako elejo kan nilu Abeokuta ti gunle ifehonu han lori isele isekupani to waye si okan lara won lasiko ti iko to n se ko kari igbokegbodo oju popo n’ipinle Ogun n se ise won.

Awn awako elejo naa ni won ko awon inkan ija bii igi gbogbo atawon inkan ija oloro miin lowo ya bo ileese awon iko naa to wa ni Ibara, ati ileese iko to n se amojuto ini igboko si ni ipinle naa, ti won si fo gilaasi awon oko ti won ba lagbegbe naa.

Won tun so pe won gbe owo ti won ko mo iye re lo nileese ajo naa.

Nigba to n b’awon oniroyin soro, Awako epo Ogbeni Soji Sehinde tun ti esun kana won osise iko naa pe won maa n lo awon lowo gbe owo, o se adayansi e pe gbigbo awon to ni oko elejo ni won paa lase fun pe won gbodo maa san egberun lona ogunrun kan naira, ley ti awon ti n san.

Nigba to n fesi, agbenuso iko TRACE n’ipinle Ogun, Ogbeni Babatunde Akinbiyi saleye wi pe iwode jagidijagan tawon awako elejo na gunle ko seyin iku okan lara won to je pe awako bii tiwon naa lo wa oko to gbemi omokunrin naa.

O salaye wipe, oko elejo naa ni won fi ofin de pe o tapa sofin isede ale, ko to dip e isele buruku naa waye.

Leyin opo wahala latoodo awon Olopa Ibara lo je ki ohun gbogbo pada bo sipo lagbegbe naa.

Babatunde Salaudeen

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *