Yoruba

Awon Agbe, Darandaran Ilu Eggua ni Ipinle Ogun Fenuko Lati Dekun Ija

Awọn agbe ati awọn darandaran ni ilu Eggua ti fẹnuko ati gbe igbimo dide lati máa wá ojutu sí orísirísi fàá kaja to ma na waye.

Igbimo ohun ni o ni awọn agbe, awọn darandaran, ati awọn agbofinro, ti yóò sì wa lati ma dènà ija ajaku akata to ma ni waye lodoodun.

Awọn igun mejeeji fi enu ohun ko nibi ipade kan ti won se nilu Tata, Ijoba Ibile Ariwa Yewá pelu awon igbimo ti Ijoba Ipinle Ogun gbe dide lori oro naa.

Àkoroyin wa Wale Oluokun ni ekunrere iroyin naa lowo.

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *