Alákoso fọ́rọ̀àbò nílẹ̀ yíì, ọ̀gágun Salihi Magashi ló sọ̀rọ̀ yíì di mímọ̀ nílu Abuja níbi àpérò ọlọ́dọdún àwọn olùbádámọ́ran pàtàkì fọ́rọ̀ àbò, èyí tájọ aláàbo ọ̀tẹlẹ̀ múyẹ́ sàgbékalẹ̀ rẹ̀.

Kò sài fàidunnu rẹ̀ hàn lórí wàhálá àwọn agbésùnmọ̀mí tófimọ́ tàwọn tón fọ́ ọ̀pá epo bó se ń gogò si.

Ó wá fọwọ́ ìdánilójú sọ̀yà pé, ìjọba àpapọ̀ ti setán láti kí ọ̀wọ́ ìwà náà bọlẹ̀ pátápátá.

Ọgagun Magashi kò sài ké sáwọn àjọ aláàbo gbogbo láti sàgbékalẹ̀ àwọn ọ̀nà àbáyọ mín-in fi gbógun tàwọn ìpèníjà tó ńbá ilẹ̀ Nàijírìa fínra.

Fọlakẹmi Wojuade

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *