Yoruba

Egbe Awon Omo Bibi Ilu Ibadan ti Sekilo Fawon Eeyan Ton Se Gboyosoyi Lori Oro Oye Ilu Ibadan Lati Gbeje

Egbe omobibi ilu Ibadan, CCII ti gbawon eeyan to fe maa da rugudu sile laarin igboro ilu Ibadan niynaju lati yago kuro nidi awon oro to ba le maa runa soro aja olubadan to wanle.

Aare Agba Egbe, CCII, Omooba Oluyemisi Adeaga logbe ikilo naa kale nibi ipade awon oniroyin to waye lori ayeye asa ilu ibadadn fun todun 2022 ati eto ifilole oju opo ero ayelijara egbe lo waye nile to wa loke aremo nilu ibadan

Omooba Adeaga wa fowo idaniloju soya fawon omobibi ilu Ibadan pe, gbogbo awon oro to rogba yi oye Olubadan kan ni yoo lojutu laipe o fikun pe, awon omobibi ilu ibadan yala lokunrin tabi lobinrin ni awon ona tiwon fi maa n yanju aawo nitunbi n nubi, nitori naa, kawon eeyan adarugudu sile naa lo so ewe agbeje mowo.

Omooba Adeaga wa tun fi kalaye re pe, ayeye okebadan atasa ni yoo waye lojo akoko ayeye ohun, ni gbongan nla Mapo leyin eyi ni irun Jimoh yoo tele ni mosalasi nla oja’ba tenumo ayajo ojo amala nile egbe CCII, to wa nilu Ibadan lojo keji ayeye asa naa.

Dada Owonikoko/Rotimi Famakin

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published.