Alakoso foro abele , ogbeni Rauf Aregbesola ti ro ilese panapana lati to ile ise ologun ofurufu lo, lori sisamulo oko ofurufu lati pana lasiiko isele pajawiri.

O soro yi lasiko yiyan bi ologun lati fi samin ifeyinti oludari agba ilese panapana ijoba apapo, omowe Lima  Ibrahim, eyi to waye ni lese panapana to wa nilu Abuja.

Ogbeni Aregbesola tun pe fun atunto lori ofin to de jiju ina si igbo nile Naijiria pelu bii isele ijamba ina sen wopo nile yi, to si tenumo pe yio dara ti ibasepo ba wa pelu ile ese ologun ofurufu lati fopin si igbo jijo.

O fikun pe ofin to de igbo jijo loye ki atungbe  yewo ko de ba, lati was nibamu pelu asiko yi to fimo , riridaju pe o fese mule.

pub-5160901092443552

Related Posts

  1. Pingback: URL

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *