Home Posts tagged ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́
News Yoruba

Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Lekun Nínú Owó Pípawọlé Lábẹ́nú

Gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀yọ, onímọ̀ ẹ̀rọ Seyi Makinde ti sọ́ọ̀ di mímọ̀ pé ìjọba rẹ̀ fún ọdún méjì àkọ́kọ́ ti mú àlékún bá owó tí wọ́n ń pa wọlé lábẹ́nú pẹ̀lú owó tótó billionu mẹ́ẹ̀dogun naira lái se àlékún owó orí. Gómìnà sàlàyé ọ̀rọ̀ yí níbi ètò kan tó wáyé nílu ìbàdàn lásìkò tón fèsì sí […]Continue Reading
Yoruba

Aráalu gbósùbà fúnjọba lórí ètò kólẹ̀kódọ̀tí ọlọ́sẹ̀sẹ̀

Àwọn olùgbé ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ti kan sárá síjọba lórí àsẹ tuntun nípa sísọ ètò kólẹ̀kódọ̀tí olósosù di ọlọ́sẹ̀sẹ̀. Wọ́n gbósùbà yi lásìkò ìfọ̀rọ̀wérọ̀ pẹ̀lú akọ̀ròyìn Radio Nigeria tó tọpinpin báwọn èèyàn se tẹ̀lé àsẹ náà si. Wọ́n tún rọ àwọn rọ àwọn aráalu pé kí wọ́n mú ìmọ́tótó àyíká wọn lọ́kunkúdùn láti fi le ja […]Continue Reading
News Yoruba

Ìjọba Ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ Pinnu Láti Mú Àgbéga Báwọn Ohun Amáyédẹrùn Láwọn Ilé-Ìwé

Ìjọba ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́, ti pinnu lórí àfojúsùn rẹ̀ láti mágbega báwọn ohun amáyédẹrùn yíká àwọn iléwe gbogbo tónbẹ nípinlẹ̀ yíì àti se àkànse kíkọ́ àwọn ilé-ìwé tó ti dẹnukọlẹ̀. Gómìnà Seyi Makinde ló sísọ lójú ọ̀rọ̀ yíì, lákokò tó ń pín ìwé ìkọ́sẹ́ lọ́fẹ fáwọn akẹ́kọ ilé-ìwé girama tọ́rọkàn nípinlẹ̀ ọ̀yọ́. Kò sài rọ àwọn […]Continue Reading
Yoruba

Ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ yio gbàlejò ìdíje ẹ̀sẹ́ kíkàn àgbáyé

Ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ ni yio gbàlejò ìdíje ẹ̀sẹ́ kínkàn àgbáyé ní ọjọ́ kẹtàdínlọ́gbọ̀n osù yí. Alága ìgbìmọ̀ tó ńse kòkárí ìdíje náà Ọlawale Okuniyi ló sísọ lójú ọ̀rọ̀ yí lásìkò tó kó ikọ̀ ìgbìmọ̀ rẹ̀ sòdí wá gbé bẹ́lìtì ìdíje náà wá han Gómìnà ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́, onímọ̀ ẹ̀rọ Seyi Makinde lọ́fìsì rẹ̀ tó wà l’Ajodi nílu […]Continue Reading
Yoruba

TESCOM: Àwọn èyàn tóní ìpèníjà ara ńfẹ̀húnúhàn ní ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́

Lóòrọ̀ òní, àwọn òsìsẹ́ ọba ni kò rọrùn fún láti wọ ilésẹ́ ìjọba ní Secretariat, Agodi ìbàdàn, lẹ́yìn tí àwọn tó ní ìpèníjà ara ńfẹ̀húnúhàn lórí ẹ̀sùn pé ìjọba dẹ́yẹ sí wọn. Akọ̀ròyìn ilésẹ́ Radio Nigeria jábọ̀ pé àwọn àkàndá ẹ̀dá yi ni wọ́n ńgbé oníruru àkọlé lọ́wọ́ láti fi ẹ̀húnúhàn wọn hàn. Àwọn tón […]Continue Reading
Yoruba

Gómìnà Seyi Makinde Sèlérí Láti Mú Inú Ẹbí Àwọn Ọlọ́pa Tíwọ́n Sekúpa Nínú Ìfẹ̀húnúhàn Dùn

Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Onímọ̀ẹ̀rọ Seyi Makinde ti sèlérí pé òun yóò ridájú pé òun dun ẹbí àwọn ọlọ́pa tíwọ́n sekúpa lákokò ìfẹ̀húnúhàn fífòpinsí ikọ̀ SARS, nínú tóun yóò sì sàtúnse sáwọn ilé-isẹ́ ọlọ́pa tíwọ́n bà jẹ́. Níbi ìpàdé àláfìa kan tí Gómìnà se pẹ̀láwọn ọ̀gá àgbà ilé-isẹ́ ọlọ́pa ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ tó wáyé lólúlesẹ́ náà, ládugbò […]Continue Reading