Gomina Ipinle Oyo, Senator Abiola Ajimobi ti gbe ibudo kan kale nilu Oyo ti yo ma yanju aawo.
Nibi ayeye idasile ibudo ohun ti won fi so oruko, Amofin kan to ti papoda Adejumo Kester.
Gomina Ajimobi so pe pataki kico ibudo to n pari awoo yi nilati ri daju pe gbogbo eyan ngbe po lalafia.
Saaju ni Alakoso Feto Idajo Nipinle Yi, Ogbeni Seun Abimbola tokasi pe ole ni egberin ejo eyi tirufe ibudo yi nyanju lododun lati igba ti isejoba to wa lode bayi ti bere.
Akoroyin ilese wa to koworin pelu Gomina, jabo pe, won tun se ifilole opopona Oyo- Akesan, Owode Iseyin, ti won si yii oruko re pada di Opona Oba Lamidi Adeyemi
Ogunkola/Sope