Yoruba

Awon olugbe Abeokuta pe fun idasile awon ile igbonse igbalode

Awon olugbe arin gbugbu ilu Abeokuta nipinle Ogun ni won ti pe fun idasile awon ile igbonse igbalode ki asa a ndawotele nigbangba o le dinku lawujo awon egba.

Awon olugbe naa ati awon wole wole pe ipe naa lasiko ti won so tenu won lori asa didawotele nigbangba eleyi to ti di asa laarin gbungbun Abeokuta metropolis, to je olu ilu ipinle Ogun.

Akoroyin wa Wale Oluokun jabo wipe ka maa dawotele nigbangba tidi asa eleyi to wopo laarin awon to ngbe ayika gbogbo agbebegbe to je kikida apata nilu Abeokuta.

Awon eniyan tiwon siwa ninu asa idawotele nigbangba nilu Abeokuta niwon wa ni awon adugbo bii Itoko, Itesi, oke aleji,oke ijemo, ilugun

Lawon agbegbe yii ilekiko pelu ile igbonse ni won fee ri bii fifi ara eni han bi eni totirise ati oju lila. 

Awon agbegbe ti asa ise igbonse si gbangba ti fidimule naa ni won je awon adugbo isenbaye ilu Abeokuta.

Die lara awon omo adugbo yii nigba tiwon n ba ile ise wa soro lori igbese to le wa owo iru iwa igbonse soju ode yii bole sowipe won gbodo bere si ni ko awon ile igbonse igbalode kaakiri ijoba ibile naa.

Gege bi won se wi, awon opolopo ile lotunseese ki won o maa lo kotogiriwo igba egbin si ladugbo kookan toro kan.

Ewe, awon to soro lori idawotele nigbangba nilu Abeokuta tun sowipe asa tiko dara yi lotun seese ko wa lati inu igbagbo won ti won wa pe fun ayipada okan laarin awon ton gbe ilu Abeokuta.

Oga wolewole kan nijoba ibile Guusu Abeokuta tiko fe ki oruko re o jade sowipe jije gaba lori owo ijoba ibile towaye ninu ijoba tokogba sile nipinle Ogun wa lara oun to koba eto imototo nijoba ibile naa.

O wa pe fun pipese awon ile igbonse igbalode laarin awon ijoba pelu awon aladani je ona kan gbogii lati reyin asa didawotele nigbangba laarin Abeokuta.

Idaniloju wa wipe ki orileede naijiria o darapo awon awujo ti asa idawotele nigbangba oti je gbajumo, tolori telemu logbodo setan ati se ojuse won. 

Wale Oluokun

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *