Olùdarí àjọ tó ń gbógun ti síse owó ìlú kúmọkùnọ nílẹ̀ yí EFCC, ẹ̀ka ti gúúsù ìwọ̀orùn ilẹ̀yí, ọ̀gbẹ́ni Friday Ebelo ti tọ́ka sí wíwa ọlà òjijì gẹ́gkbí oun tó ńse okùnfà bí àwọn ọ̀dọ́ 

Se ńlọ́wọ́ sí ìwà jìbìtì àti àwọn ìwà ìbàjẹ́ min tó fara pẹ́ẹ̀.

Ọgbẹni Ebelo sọ̀rọ̀ yí di mímọ̀ nígbàtí ó ńkópa lórí ètò ilé isẹ́ wa Radio Nigeria kan lédè gẹẹsi.

Óní wíwá ọ̀nà ẹ̀bùrù àti lọ́wọ́ ti múkí ọ̀pọ̀ àwọn ọ̀dọ́ yan isẹ́ tí ó bófinmu láàyo.

Ọga àjọ EFCC, ọ̀ún wá késí àwọn òbí láti máà bójútó àwọn ọmọ wọn dáàda nípa bíbẹ̀wọ́n wò láiro tẹ́lẹ̀ nílé wọn àti nípa jíjẹ́ àwòkọ́se rere fún wọn lọ́nà àti sàseyọ́rí láyé.

Ogbẹni Ebelo nu, àjọ EFCC, àti àwọn ilé ẹ̀kọ́ gíga tí ńfọwọ́sowọ́pọ̀ láti máà la àwọn ọ̀dọ́ lọ́yẹ̀ lórí ewu tó wà nínú àwọn ìwà àjẹbánu.

Dada/Alamu

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *