Yoruba

Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọyọ laago ìkìlọ̀ fáwọn tó kọ́lé lái gbàsẹ

Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọyọ ti késí àwọn tóní ilẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ọyọ, láti lọ gba gbogbo ìwé àsẹ tóyẹ kí ilé wọn mábadi gbígbẹ̀sẹ̀lé tàbí wíwó irúfẹ́ ilé náà.

Alákoso fọ́rọ̀ ilẹ̀ ilégbe àti ìdàgbàsókè àwọn ìlú ńlá-ńlá, ọ̀gbẹ́ni Abiọdun Abdu-Raheem sọ èyí lákokò tó sàbẹ̀wò sáwọn ibùdó tójẹ́ tìjọba nílu ìbàdàn, pẹ̀lú àlàyé pé, ìjọba tówà lóde báyíì, sífẹ sọ̀rọ̀ ilẹ̀ jákè-jádò ìpínlẹ̀ Ọyọ fún àkọsílẹ̀ tógúnmọ́.

Ọgbẹni Abdul-Raheem wá tọ́kasipé, ilésé náà yóò máà sàbẹ̀wò àiròtẹ́lẹ̀ sáwọn ibùdá lọ́kanòjọ̀kan láti mọ̀ bóyá wọ́ọ́ní àsẹ tóóyẹ.

Kẹmi Ogunkọla/Adebisi Iyabọ

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *