Yoruba

Egbe osise se ijiroro lori afikun owo epo bentiro

Egbe osise ta mo si TUC, lo tin jiroro Po pelu ijoba atawon Toro kan lati yo afikun iye owo Lori epo bentiro ati Ina oba kuro si iye to wa tele.

Alaga egbe naa nipinle osun, Ogbeni Adebowale Olubunmi lo je koro yi di Mimo fawon akoroyin nilu ilesa.

Alaga tokasi pe egbe TUC koni fowo leran, to so salaye pe  aboo ipade ati ijiroro olokanojokan pelu awon torokan ni yo so pato igbese tawon osise ataralu yo gbe.

Nigba ton soro Lori oniruru awon ifehonuhan tawon akeko ngunle lori afikun iye owo bentiro ati Ina oba, Ogbeni Olubunmi be awon akeko ki won ni suru, ki won si ma faye gba kawon omo isota gba ifehonuhan naa mo won lowo.

Afolabi/Afonja

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *