Yoruba

Ijoba Apapo Kilo F’Awon Eeyan Lori Ayedaru Abere Ajesara COVID-19

Alakoso feto Ilera, Dokita Osagie Ehanire ti sekilo fawon eyan Ile Naijiria lati kiyesara, pelu bi won ti se n ko ayederu abere ajesara wo opo olire ede.

Dokita Ehanire, soro ikilo yi lasiko to lo se abewo si ilewosan ti won tin setojju enito ba ni arun opolo to wa ni Yaba nipinle Eko, o to kasi pea won kolorosi eda kan nlo anfani bawon eeyan se n fe, ajesara ohun lati pese ayederu re.

Alaksoso ni ile Naijiria sin reti lati gba abere ajesara lati ile ajesara lati ile Russia larin ose meji si meta to n bo.

Alakoso feto ilera, wa fikun oro re pe, awon ojise eleto ilera, ni won yow a lara igun akoko ti won yo gba abere naa, nitoripe awon ni won koju ipenija julo lasiko ti won n se itoju eni to ti ni arun COVID-19.

Ololade Afonja/Blessing Okareh

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *