Yoruba

Iko Agbebon Ji Odunrun Awon Omoleewe Obinrin N’ipinle Zamfara Gbe

Iko ajinigbe ti gbe awon akekobinrin to je odunrun niye n’ilewe Government Girls Secondary School, Jangebe, n’ipinle Zamfara.

Iroyin fidi e mule pe amugbalegbe pataki lori lila araalu loye, Ogbeni Zailani Bappah lo fidi isele naa mule f’awon akoroyin ni Zamfara.

Isele yi lowaye leyin ose kan ti won ji akeko mejilelogun atawon osise nilewe kan ni kagara, nipinle Niger.

Awon ajinigbe yi, ni won wo aso ologun lati sise nla ibi won lose to koja lara awon ti won jigbe nipinle Niger latiri akeko kurin metadinlogbon ati oluko meta.

Ololade Afonja/Blessing Okareh

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *