Alakoso foro irohin atoro ton lo nipinle niger alhaji sani idris ni awon ajinigbe ti gbe lo.

Akowe agba sijoba ipinle niger alhaji ahmed matane lofidi ijinigbe naa mule nilu abinibi re baban tunga, nijoba ibile  tafa nipinle naa.

Alhaji matare so pe awon iko alabo to lepa awon ajinigbe yi, ti gbagbo si wa pe, won koni pe doola re, lakata awon ajinigbe.

Afonja

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *