Environment

Awon Onimo Nfe Ki Aabo To Peye Wa Lori Ayika,Lati Dena Ayipada Oju Ojo

Awon akopa lori eto ileese Radio Nigeria, Ibadan tiwon pe lede geesi ni focal Point n fe ki ajosepo to munadoko wa lori didabobo ayika lati dena ayipada oju ojo.

Awon akopa lori eto, lo soro yi lasiko ti won soro lori ayajo ojo moniyan lagbaye, pelu alaye pe ipa ti omoniyan nko lori ayika, lo n nfa oniruru ipenija lagbaye.

Akowe egbe alagbelebu pupa nile yi, teka ipinle Oyo, Ogbeni Olaleye Ojo tokasi pe ohunkohun to ba sakoba fun ayika, ni yo koba omoniyan.

Alamojuto egbe ti won pe lede geesi ni Family RESORE, Ogbeni Kayode Omoseyi ro awon eniyan lati gunle awon ise ti yo mu amugboro de ba ounje.

Won wa rawo ebe sijoba lati fie to abo to peye lele, ti yo run mu amugboro de ba eto ogbin nile yi.

Ololade Afonja

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *