Ajọ ton rí soro dúkìá bẹ̀rẹ̀ sini ṣe àyẹ̀wò ikede Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́
Níbamu
àjọ ton rí soro kikede dúkìá ẹni, tí bẹ̀rẹ̀ sini ṣe àyẹ̀wò dúkìá oni bilionu
mejidinlaadota náírà èyí tí Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, onímò ero Seyi Makinde kéde
rè losu kẹfà ọdún yìí.
Olùdarí
àjọ náà ńipinle Ọ̀yọ́, Ogbeni Bisi Atolagbe ló sísọ lójú ọ̀rọ̀ yìí nilu Ìbàdàn,
lákòókò ìpàdé àwọn adarí àjọ náà fẹ́ kún iwoorun gusu pẹ̀lú ọmọ ẹgbẹ́ ton ṣojú
ẹkùn àjọ náà nínú ìgbìmò CCB, Ojogbon Samuel Ogunda rẹ.
Ojogbon
Atolagbe sọ pé, òun ti fi isiro iye dúkìá náà sowo sì olulese àjọ òhun tó wà nilu
Abuja, teto ayẹwo náà sì ti bẹ̀rẹ̀ lèyẹ osoka.
Kò
sai tókasi pé, ó ṣe ṣe kí ètò náà fale ranpe nítorí àwọn abala kan nínú ètò
ayẹwo náà tó lọ́wọ́ ìmò ẹ̀rọ nínú tó sí ṣèlérí wípé ní kété tayewo òhun bá parí
niwọn yóò kéde rè síta.
Adebisu/Ogunkola.