Yoruba

Ijoba Ipinle Ekiti Kilo Lori Iwa Odaran

Gomina Ipinle Ekiti, Omowo Kayode Fayemi ti kilo fawon odaran nipinle naa lati ronu piwada tabi ki won foju wina ofin.

Gomina fayemi fi ikilo yi sita ni Ilu Ikere Ekiti nigbati o nsi ago olopa  kan.

Gomina eniti olubadamonran Pataki si lori oro aabo, ogagun Ebenezer ogundana soju fun wa kilo fawon eniyan lati yago fun awon iwa odaran, o wa tenumo wipe won o ni faaye gba ki enikeni da ibasepo alaafia ipinle naa ru.

Gomina Fayemi so wipe odaran eyikeyitowo ba te ni lo laijiya labe ofin.

 NET/Dada

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *