Aare nigbakanri nile yi, Omowe Goodluck Jonathan ti kesi awon omo ile yi lati nireti ninu ojo ola ile Nigeria lai nani awon ipenija to n koju lowo.

Omowe Jonathan soro naa ninu atejade to fisita nilu Abuja fawon eeyan ile yi fun ayeye Ominira odun mokanlelogota.

O sapejuwa ayajo ominira ohun gege bi ojo idande, lati safihan ilosiwaju, ile Nigeria to fimo ayeye aseyori to ti se ati lati ko giri mo awon afojusun re.

Aare teleri ohun wa gba awon adari ilu atawon omo ile ye niyanju lati farawon jin lori ipindogba, idajo ododo, ikora eni mora, ati ilakaka fun sisapa won fun rere ile yi.

Aare ana nileyi ro awon omo ile Nigeria lati maa nireti ninu ojo ola.

Blessing Adesanya/Ayodele Olaopa 

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *