Kodin ni opo bi eedegberin, 700, ti janfani eto ironilagbara ti ofisi   aya gomina ipinle Oyo, Arabinrin Tamunomini Makinde gbe kale fun mimu    iderun bawon.

Nigba to n soro nibi eto ohun to waye nileegbe ijoba to wa Lagodi, nily Ibadan, Arabinrin Makinde wa gba awon opo niyanju lati sise lori diduro lori owo arawon ki won le maa gbo bukata awon omo won.

Arabinrin Makinde to ro awon eleyinju aanu awujo lati maa sanu awon opo, atawon to ku die kato fun lawujo, salaye pe sise bee yoo maa fun won lanfani sise amuse ala won.

Ewe ninu oro ikini kabo re alamojuto foro akansi ise nipinle Oyo, Arabinrin Fausat Sanni nigha to n tenumo afojusun ijoba to n be lode lori sesranwo fawon opo waro won lori ninireti fawon afojusun won.

Awon opo meji, Arabinrin Maryam Sheriff ati Arabinrin Lizzy Okubo war o awon eeyan lati maa ji giri si amuse afojusun awon opo ki won maa ba di nkan ti o wulo mo leyin iku oko won.

Eto ironilagbara to waye jakejado ijoba ibile metalelogbon ipinle Oyo ni e to pinpin ounje bi iresi, ewa, gaari, ororo ati agolo afefe gaasi ti waye fawon opo.

Ayodele Olaopa

pub-5160901092443552

Related Posts

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *