Home Archive by category Yoruba (Page 2)

Yoruba

Yoruba

Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó bẹ̀bẹ̀ fún ìgbọ́raẹniyé lórí owó ẹnu ìloro Lẹ́kkí

Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkó ti pàrọwà fáwọn onímọ̀tó láti ní ẹ̀mí ìgbọ́raẹniyé lórí bí wọ́n tise ńgberò àti bẹ́ẹ̀rẹ̀ síì gbowó padà lẹ́nu ìloro Lẹ́kkí. Alákoso fọ́rọ̀ ìròyìn nípinlẹ̀ Èkó ọ̀gbẹ́ni Gbenga Ọmọtọsọ ló pàrọwà yí nílu Èkó. Ọgbẹni Ọmọtọsọ tẹnumọ́ ìdí tí àwọn olùgbé ìpínlẹ̀ Èkó fi gbọdọ̀ máà fojú áànu wo àwọn òsìsẹ́ ẹnu […]Continue Reading
Yoruba

Ẹgbẹ́ CIIN ti ní Adarí Tuntun

Ẹgbẹ́ àwọn akọ́sẹ́mọsẹ́ lórí adójútófo nílẹ̀ yí CIIN ẹ̀ka tìpińlẹ̀ ọ̀yọ́ ti búra fún àwọn ọmọ ìgbìmọ̀ tuntun. Ètò yí tó wáyé níbi ayẹyẹ ìfàmìẹ̀yẹ dáni lọ́lá àti ìgbaniwọlé ọlọ́lọọdún wọn tó wáyé nílu ìbàdàn ni wọ́n ti búra fún ọ̀gbẹ́ni Ọladeji Akinọla gẹ́gẹ́bí alága àti àwọn ọmọ ìgbìmọ̀ mẹ́jọ min tí wọn yio tukọ̀ […]Continue Reading
Yoruba

Ẹgbẹ́ Àwọn ọmọ Ilẹ̀ Yí Nílẹ̀ Òkèèrè Bèèrè Fátìlẹyìn Ìjọba Lórí Àwọn Akẹ́kọ Tó Sá Kúrò Ní Ukraine

Alága ẹgbẹ́ àwọn ọmọ ilẹ̀ Nàijírìa lókèèrè, ẹ̀ka ti orílẹ̀ èdè Hungary, ọ̀mọ̀wé Hussaini Argungun ti bèèrè fún àtìlẹyìn ilésẹ́ ìjọba àpapọ̀ fọ́rọ̀ amujo ìjàmbá àti mímú ìdẹ̀rùn bá ará ìlú lórí àwọn akẹ́kọ ọmọ olẹ̀yí tí wọ́n sá kúrò ní Ukraine kí wọ́n báà le dúró ní Hungary. Ọmọwe Argungun ẹnití ó ńbá ilé […]Continue Reading
Yoruba

Asòfin Bèèrè Àfikún Ògbómọ̀sọ́ Nínú Orúkọ LAUTECH Tí Wọ́n Fẹ́ Yípadà

Àbá òfin láti sàyípadà ilé ẹ̀kọ́ gíga ìmọ̀ ẹ̀rọ Ládòkè Akintọla, LAUTECH, sí ilé ẹ̀kọ́ tí wọ́n ti ńkọ́ ìmọ̀ gbogbogbò ni wọ́n ti kà fún ìgbà kejì nílé ìgbìmọ̀ asòfin Ìpínlẹ́ ọ̀yọ́. Èyí ló jẹ́ nítorí ìwé kan tí Gómìnà Seyi Makinde fi sọwọ́ sílé ìgbìmọ̀ asòfin tí adarí ilé, ọ̀gbẹ́ni Adebọ Ogundoyin kà […]Continue Reading
Yoruba

Àjọ FRSC Pàrọwà Fáwọn ọmọ Ilẹ̀yí Lórí Àyípadà Ìwà

Àjọ ẹ̀sọ́ ojú pópó, FRSC, ti ní lílo ìlànà ìmọ̀ ẹ̀rọ ìgbàlódé tí múkí ọwọ́ isẹ́ túbọ̀ yá kánkán àti jáfáfá síì léyití ó ti jẹ́kí àdínkù dé bá àwọn ìjàmbá ojú pópó. Ọga àgbà àjọ FRSC, ọ̀mọ̀wé Boboye Oyeyẹmi ló sọ̀rọ̀ yí di mímọ̀ níbi ìdánilẹ́kọ kan tó wáyé nílu Abuja. Ọmọwe Oyeyẹmi wá […]Continue Reading
Yoruba

Àarẹ Buhari Sèlérí Láti Wá Ojútu Sọ́rọ̀ Ilégbe Fáwọn Èèyàn Tọ́rankan

Àarẹ orílẹ̀dè yíì, Muhammadu Buhari ti sọ́ọ̀di mímọ̀ pé, ìsèjọba òun ti n wójùtú sọ́rọ̀ ilégbe fáwọn ọmọ orílẹ̀dè yíì, papajùlọ àwọn tó ń gbé láwọn ìlú ńlánlá. Lákokò tó ń sèfilọ́lẹ̀ àwọn isẹ́ àkànse ilégbe, abala àkọ́kọ́ nílu Òsogbo, tí sólùlú ìpínlẹ̀ Ọsun, áàrẹ sísọ lójú ọ̀rọ̀ náà. Áàrẹ Buhari ẹnití alákoso fọ́rs abẹ́lé, […]Continue Reading
Yoruba

Agbẹjọ́rò Dába Òfin Lati Dekun bi Awon Gomina Se Nsi Lo Si Egbe Miran

Agbẹjọ́rò kan, ọ̀mọ̀wé Kazeem Olaniyan ti gbàwọn  ọmọ ilé- ìgbìmọ̀ asòfin àpapọ̀ níyànjú láti tọwọ́ òfin tóníse pẹ̀lú káwọn asojú kan bo somun bọnú àtúnse ìwé òfin tónlọ lọ́wọ́. Ọmọwe Ọlaniyan tótún jẹ́ olúkọ̀ lẹ́ka tíwọ́n tin kọ́ nípa ìmọ̀ òfin nílé ẹ̀kọ́ gíga fásitì ìbàdàn ló gbọ̀rọ̀ àmọ̀ràn yíì kalẹ̀ lákokò tó ń kópa […]Continue Reading