Egbe awon obinrin oniroyin nile nigeria NAWOJ eka tipinle ogun ti gba awon obi niyanju pe ki won kilo fawon omo won lori gbigba ebun ofe to lee ko won siyonu laako ayeye ayajo ololufe. Ipolongo ilaniloye naa lo gbe awon omo egbe NAWOJ lo sile ijosin lolokan ofokan pelu awon oja nilu Continue Reading
Yoruba
Nidi igbiyanju ati mu agbega ba ipese isu lopo yanturu , ile ise ton risi idagbasoke ise agbe nile olooru, IITA ti se agbekale ona igbalode fun ipese eebu isu ti kokoro ko ni le je . aseyori yi lo jeyo latara akanse ise ti won da pe ni agbega isu fun ipawo wole ati […]Continue Reading
Oludamoran pataki fun aare Muhammadu Buhari lori ona lati mu iderun ba eto okowo omowe Jumoke Oduwole ti kesi awon omo ile yi pe ki won maa lo eroja aso to ba je ojulowo ti won n pese lorileede yi. Omowe oduwole pepe yi lasiko abewo enu ise to se si gomina ipinle ogun, omooba […]Continue Reading
Ijoba ipinle Oyo ati ile ise to nrisi pinpin ina oba nilu Ibadan IBEDC, ti yanju awoo to mu ki won ti lara ile ise ton npin na. Leyin ipade to waye laarin ijoba ati IBEDC ni ile ise ijoba ipinle Oyo to wa l’Agodi nilu Ibadan,ni , ni awon mejeeji so pe won setan […]Continue Reading
Alakoso foro abele , ogbeni Rauf Aregbesola ti ro ilese panapana lati to ile ise ologun ofurufu lo, lori sisamulo oko ofurufu lati pana lasiiko isele pajawiri. O soro yi lasiko yiyan bi ologun lati fi samin ifeyinti oludari agba ilese panapana ijoba apapo, omowe Lima Ibrahim, eyi to waye ni lese panapana to wa […]Continue Reading
Ajo eleto idibo nile yi, INECti kesi awon eeyan ile Nigeria lati pari iforukosile won feto idibo loju ojo leyin iforikosile ori eto ayelujara. Olori leka idanileko ati oro-awujo lajo INEC nipinle Oyo, Arabinrin Catherin Ogwu so eyi lasiko to n kopa lori eto ilese Radio Nigeria kan Political Space. Arabinrin ogwu ni, iye awon […]Continue Reading
Awon osise leka irin ajo ofurufu ni won ti sewele, erongba won lati gunle iyanselodi eyi ti won fe bere loni. Igbese yi lo waye leyin ti won ti fenu ko pelu awon osise ati ajo to n risi irin ajo ofurufu. Igun mejeeji lo fowo si afenuko leyin ipade lati yanju aawo, eyi ti […]Continue Reading
Ajo UNICEF pelu ibasepo Ajo ti kii se tijoba ni won ti gbe iko to yo ri daju pe opin deba didabe fomobinrin nileyi lele. Ogaagba ajo ti kii se ti joba, ‘One life initiative for human development Ogbeni Sola Fagorusi lo soro yi di mimo lasiko to n kopa lori eto iforowa nilenuwo ilese […]Continue Reading
Gomina Banki agba ile Nigeria CBN, Ogbeni Godwin Emefiele ti ro awon ile ise to n risi ipese iresi nile yi lori igbawole eto ti banki naa gbe kale fun gbigbon wo si ipawo wole nile Nigeria. Ogbeni Emefiele soro yi nibi eto kan to waye nipinle Kano. O salaye pe irufe eto bee yoo […]Continue Reading
Ile igbimo asofin ipinle Oyo ti roe ka alase nipinle Oyo lori titejade ohun ifilede gbogbo aba tile igbimo ohun ti so dofin. Ipe naa lo tele oro lori Pataki tetejade to fi mo fifelede awon ofin ohun ti asofin to n soju ekun idibo Ariwa Ogbomosho, Arabinrin Olawumi Oladeji gbe siwaju ile. Nigba to […]Continue Reading
Ilese olopa nipinle oyo, ti bere igbese fifofinde lilo oko yafun yafun , siren, lona aito, lilo awon number idanimo oko ti won boo, lilo oko to ayee awako wa lowo otun tofimo oko ti eto ifonikosile re oti waye. Eyi jeyo ninu atejade kan, eyiti agbenuso ilse olopa nipinle oyo, ogbeni olawale osifeso fowosi […]Continue Reading
Gomina ipinle Oyo Onimoero Seyi Makinde ti siso loju ise siso akanse opopona oni kilometre mesan ole die Oke Ogun Poly, ilu Saki Ilesa-Ibariba di onibeji. Gomina Ahmadu Fintiri ti ipinle Adamawa tii se alejo pataki nibi eto naa, gboriyin fun Gomina Makinde fun ise akanse ohun atawon nkan amayederun miran laifi ti ipenija oro […]Continue Reading
Oga agba ajo to n risi itaniji araalu N.O.A nipinle Oyo, Arabinrin Folake Ayoola ti pe fun ajosepo to dan moran laarin ajo ohun ati ile ise Radio Nigeria. Arabinrin Ayoola salaye pe riro ajosepo larin ile ise mejeeji lagbarasi lose koko fun ise won fawon araalu papa julo pelu bile yi se n gbaradi […]Continue Reading
Ijoba apapo ti so di mimo pe yoo to osu mejidinlogun sasikoyi kohun to le yoo owo iranwo epo robi. Alakoso keji foro epo bentiro, Ogbeni Timpre Silva lo soro naa nilu Abuja lasiko to n baa won akoroyin ile ijoba fowowewo loti oro naa. Alakoso ohun salaye pe oro lori yiyo owo iranwo epo […]Continue Reading
Nidi ati wa ona abayo si isoro awon ewe to sa kuro nileewe lorileede yi, o se Pataki fawon toro eto eko gberu lati maa fowosowopo. Alaga ajo eleto eko kariaye nipinle Oyo, Omowe Nureni Adeniran lo pepe yi lasiko iforowero pelu akorinyin Radio Nigeria fun ti isami ayajo eto eko lagbaye. Omowe Adenitan kominu […]Continue Reading
Won ti gba ijoba apapo nimoran pe ki won sewele erongba afikun owo epo petirolu farailu nipa ati yo owo iranwon ori epo wo. Oluso Aguntan ile Ijosin C.A.C. Power of the Cross, to wa lagbegbe Orogun nilu Ibadan, Pastor Joshua Aghene lo soro imoran yi lasiko takoroyin Radio Nigeria n foro wa lenuwo nipa […]Continue Reading
Adari ile asofin apapo keji Ogbeni Femi Gbajabiamila tip e fun idasile Banki eto eko lona ati le maa pese owoya irorun ti ko ni ele fawon akeko to wa nile eko giga nipa ati le mu eto eko rorun fun tolori telemu. Adari ile asofin tun pe fun agbende liana eto eyawo fawon akeko […]Continue Reading
Ijoba apapo ti soo di mimo wi pe won yoo se idasile ebu ifopo esekuku meta otooto si okookan ati ipinle to n pese epo robi lagbegbe Niger/Delta. Alakoso keji foro ayika nile yi, Oloyo Sharon Keazor lo sipaya oro yi ninu atejade to fi sita nilu Abuja. O salaye wipe, awon ebu ifopo […]Continue Reading
Egbe omobibi ilu Ibadan, CCII ti gbawon eeyan to fe maa da rugudu sile laarin igboro ilu Ibadan niynaju lati yago kuro nidi awon oro to ba le maa runa soro aja olubadan to wanle. Aare Agba Egbe, CCII, Omooba Oluyemisi Adeaga logbe ikilo naa kale nibi ipade awon oniroyin to waye lori ayeye asa […]Continue Reading
Ondo State Governor, Mr. Oluwarotimi Akeredolu, SAN, has approved the appointment of Chief Adetunji Adeleye as his Special Adviser on Security Matters. The appointment takes immediate effect. Chief Adeleye will, however, continue to function as the Commander of the Ondo State Security Network (Amotekun Corps). The appointment is part of the efforts of the Governor […]Continue Reading
Alakoso foro abele, Ogbeni Rauf Aregbesola ni, ogba atunse towa ni agbegbe Oloju-Oro, Olomi nilu Ibadan yoo bere sin je sisamulo losu keta odun yii. Alakoso so eyi lasiko to sabewo si, Ogba Atunse, Agodi, Ibadan ati agbegbe Olomi. O salaye pe, Ogba atunse Olomi yi tise tife pari lori re, yoo gba to awon […]Continue Reading
Olujabo bere idaraya se nlo lori papa titun se, agbenu so nigbakan ri fegbe agbaboolu Shooting Star, Ogbeni Jubril Arowolo, ti fenu sipe igbese to dara gba ni, gbigba awon akonimogba labele fegbe agbaboolu Super Eagles. Ogbeni Arowolo so leyi di mimo lasiko to nko pa lori eto ilese Premier FM 93.5, Straight Talk. Ogbeni […]Continue Reading
Igbimo Olubadan to fenuko lati maa jee Oloye agba dipo Oba Alayeluwa. Nigba to n baa won akoroyin soro leyin ipade to waye ni afin Ojaba ti Olubadan ile, Ibadan, Oloye Tajudeen Ajibola so pea won gba igbese gomina lori ipinu re lati da awon pada sori jije Oloye agba. Lori oro to si w […]Continue Reading
Ijoba apapo ti so pe ko si ooto ninu iroyin to n ja rohinrohin pe aarun romolapa romolese ti be sile lawon ipinle kookan. Ijoba fowo idaniloju re soya pe ko ti si isele aarun naa tuntun nile yi lati odun 2016. Ogaagba eto idagbasoke ilera alabode, Dokita Faisal Shuaib eni to ni ko si […]Continue Reading
Ajo to n risi eto idanwo igbaniwole sawon ile-eko giga, JAMB, ti sope,oun ti pari gbogbo eto lori awon ibudo idanwo ni gbaradi feto idanwo UTME todun 2022. Eyi lo jeyo ninu atejade kan tajo JAMB fisita fawon oniroyin. Igbimo oludanwo naa ko sen tun soodi mimo pe, eka to ri soro imo ero lajo […]Continue Reading