Home Archive by category Yoruba (Page 34)

Yoruba

Yoruba

Ètò àpérò ọlọ́jọ́ mẹ́ta tí ílesẹ́ Radio Nigeria ìbàdàn kásẹ̀ nílẹ̀

Ètò àpérò ọlọ́jọ́ mẹ́ta lórí àwọn ǹnkan tí yóò máà jáde lórí afẹ́fẹ́ nílesẹ́ Radio Nigeria ìbàdàn ti kásẹ̀ nílẹ̀ ní Ìlárá Mọ̀kín, nípinlẹ̀ Òndó. Àwọn olùkópa láwọn ẹ̀ka ilé-isẹ́ náà, yíká ẹkùn gúsù ìwọ̀orùn ilẹ̀ yíì, ló péjú pésẹ̀ síbẹ̀. Nínú ìdánilẹ́kọ kan tó gbékalẹ̀ èyí tíwọ́n pe àkòrí rẹ̀ ni, mímú àgbéga bá […]Continue Reading
Yoruba

Ilé ẹjọ́ sún ìgbẹ́jọ́ Gómìnà síwájú ńipinlẹ̀ Ọsun

Ilé ẹjọ́ tó ńgbọ́ awuyewuye tó súyọ lásìkò ìdìbò sípò Gómìnà nípinlẹ̀ Ọsun èyí tó jóko nílu Abuja, ni yo gbe ìdájọ́ kalẹ̀ lọ́jọ́ ẹtì tónbọ̀ yi, lórí ẹ̀sùn èyí tí ẹni tó díje lábẹ́ àsía ẹgbẹ́ òsèlú Peoples Democratic Party, PDP, Sẹ́nátọ̀ Ademọla Adeleke, lórí àbájède ìbò tó wáyé nínú osù kẹsan, ọdún tó […]Continue Reading
Yoruba

Gómìnà Tuntun Sèlérí Láti Mú Àgbéga bá Ètò Ìròyìn

Gómìnà Ọyọ tílu sẹ̀sẹ̀ dìbò yàn, ọ̀gbéni Seyi Makinde ti sọ pé òfin tó fàyè sílẹ̀ fáwọn èyàn láti ní ẹ̀tọ́ sí ìròyìn àtọ̀rọ̀ tónlọ se pàtàkì àti wípé yo mu àgbéga bá káwọn èyàn ma dásí ètò ìsèjọba nípinlẹ̀ yi. Ó sọ̀rọ̀ yi nígbàtí ikọ̀ ìgbìmọ̀ alásẹ ilésẹ́ Radio Nigeria, èyí tí ọ̀gágba fún […]Continue Reading
Yoruba

Àarẹ Buhari késí ọmọ ilẹ̀yí láti díbò lái fa wàhálà

Àarẹ Muhammadu Buhari ti késí àwọn èèyàn ilẹ̀ Nàijírìa láti tú yáyá jade láti kópa nínú ètò ìdìbò Gómìnà àti ti-ilé ìgbímọ̀ asòfin Ìpínlẹ̀ tí yóò wáyé lọ́jọ́ àbámẹ̀ta yi. Àarẹ rọ tikere tikere ọmọ ilẹ̀ yi láti jẹ́kí ètò ìdìbò náà lọ nírọwọ́-rọọsẹ̀ gẹ́gẹ́ bí tétò ìdìbò sípò àarẹ se lọ láisi jàgídí-jàgan. Àarẹ […]Continue Reading
Yoruba

Òjísẹ́ Ọlọ́run pè fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ìjọba tuntun

Àgbàgbà Bishop tìjọ Anglican lẹ́kùn Èkó, ẹni-ọ̀wọ̀ Humphrey Ọlumakaiye ti rọ gbogbo ọmọ ilẹ̀ yí láti gba ìyànsípò padà Àrẹ Muhammadu Buhari gẹ́gẹ́bí isẹ́ Ọlọ́run. Ẹni-ọ̀wọ̀ Olumakaiye ló sọ̀rọ̀ yi nípinlẹ̀ Èkó, lásìkò tón bá akọròyìn ilésẹ́ Radio Nigeria sọ̀rọ̀. Ó sọ wípé Ọlọ́run gan ló yan Àrẹẹ Buhari fún orílẹ̀èdè Nàijírìa, ó wá rọ […]Continue Reading
Yoruba

Àjọ elétò ìdìbò fi aráalu lọ́kàn balẹ̀ lórí ìdìbò

Àjọ elétò ìdìbò ilẹ̀ yíì,INEC, sọpé mìmì kankan kòní mì ètò ìdìbò sí ipò Àarẹ láifi ti iná ọmọ rara tó bá àwọn ẹ̀rọ asayẹ̀wò cárdi oludìbò kan jẹ. Alága àjọ INEC, ọ̀jọ̀gbọ́n Mahmood Yakubu, sọ èyí di mímọ̀ nígbà tó sèfilọ́lẹ̀ ibùdó kan táwọn ẹgbẹ́ ajàfẹ́tọ ọmọnìyàn yóò ti máà tọpinpin ètò ìdìbò. Ọga […]Continue Reading