Home 2019 (Page 2)
Yoruba

Apero àwọn Gómìnà pè fún ilaniloye lórí ọ̀rọ̀ kobakungbe

Apero àwọn Gómìnà nílè yíì, NGF, tí gba ilé ìgbìmò asofin àgbà ilé yíì níyànjú láti gunle ìpàdé ìta gbangba lórí àbá òfin kan tonise pẹ̀lú sísọ ọ̀rọ̀ kobakungbe láti rí dájú pé, wón gbo èrò aráàlú lórí àbá òfin náà. Alága Apero àwọn Gómìnà ohun, tí í ṣe Gómìnà ìpínlè Sokoto, Aminu Tambuwa ló Continue Reading
Yoruba

Onímọ̀ ìsègùn késí àwọn èèyàn lórí àbójútó ìlera

Wọ́n ti rọ àwọn èèyàn ilẹ̀ yíì, láti ma sọ́rase lórí ìgbé-ayé wọn àti irúfẹ́ ónjẹ tí wọ́n yóò ma jẹ, lọ́nà àto dènà bíbọ́ sí pánpẹ́ àisàn ìtọ̀ súgàr. Àarẹ ẹgbẹ́ àwọn tóní ìtọ̀ sugar, olóyè Emmanuẹl Adeyinka sọ̀rọ̀ àmọ̀ràn yíì níbi ètò àyẹ̀wò ìlera ọ̀fẹ́ ọlọ́jọ́ kan, èyítí ẹgbẹ́ àwọn olùgbé Continue Reading
Yoruba

Aisha Buhari se ìpolongo ìgbógúnti ìkú ìyálọ́mọ

Aya àarẹ ilẹ̀ yíì, Arábìnrin Aisha Buhari ti sèfilọ́lẹ̀ ètò ìpolongo tó dá lórí àti jẹ́kí ìrẹ́pọ̀ wà láarin àwọn abiyamọ àtàwọn ọmọ tuntun, pẹ̀lú ètò ìlara àwọn èwe tófimọ́ dídènà àisàn ibà, àti sisọnọ lórí óunjẹ afáralókun lábẹ́ ètò kan soso. Arábìnrin Buhari ẹnití aya Gómìnà ìpínlẹ̀ Kẹbbi, Continue Reading
Yoruba

Ilé ẹjọ́ fagilé àgbéga àwọn ọba mọ́kànlélógún nílu ìbàdàn

Lẹ́yìn osù mẹ́tàléláadọta tí wọ́n sàgbéga fún àwọn ọba kan nílu ìbàdàn látọ̀dọ̀ Gómìnà àná nípinlẹ̀ Ọyọ Sẹnatọ Abiọla Ajimọbi, ilé ẹjọ́ gíga ti ìpínlẹ̀ yí ti wọ́gilé ilé ìwé òfin tí wọ́n tẹ̀lé láti sàgbéga ọ̀hún. Nígbàtí ńfọwọ́sí àdéhùn yíyanjú ẹjọ́ tí ìjọba ìpínlẹ̀ yi àti èyí tí òsì Olúbàdàn Continue Reading