March 20, 2019
Home NEWS Archive by category Yoruba

Yoruba

Yoruba

Àarẹ Buhari késí ọmọ ilẹ̀yí láti díbò lái fa wàhálà

Àarẹ Muhammadu Buhari ti késí àwọn èèyàn ilẹ̀ Nàijírìa láti tú yáyá jade láti kópa nínú ètò ìdìbò Gómìnà àti ti-ilé ìgbímọ̀ asòfin Ìpínlẹ̀ tí yóò wáyé lọ́jọ́ àbámẹ̀ta yi. Àarẹ rọ tikere tikere ọmọ ilẹ̀ yi láti jẹ́kí ètò ìdìbò náà lọ nírọwọ́-rọọsẹ̀ gẹ́gẹ́ bí tétò ìdìbò sípò àarẹ se lọ láisi Continue Reading
Yoruba

Òjísẹ́ Ọlọ́run pè fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ìjọba tuntun

Àgbàgbà Bishop tìjọ Anglican lẹ́kùn Èkó, ẹni-ọ̀wọ̀ Humphrey Ọlumakaiye ti rọ gbogbo ọmọ ilẹ̀ yí láti gba ìyànsípò padà Àrẹ Muhammadu Buhari gẹ́gẹ́bí isẹ́ Ọlọ́run. Ẹni-ọ̀wọ̀ Olumakaiye ló sọ̀rọ̀ yi nípinlẹ̀ Èkó, lásìkò tón bá akọròyìn ilésẹ́ Radio Nigeria sọ̀rọ̀. Ó sọ wípé Ọlọ́run gan ló yan Àrẹẹ Buhari fún orílẹ̀èdè Nàijírìa, ó wá rọ […]Continue Reading
Yoruba

Àjọ elétò ìdìbò fi aráalu lọ́kàn balẹ̀ lórí ìdìbò

Àjọ elétò ìdìbò ilẹ̀ yíì,INEC, sọpé mìmì kankan kòní mì ètò ìdìbò sí ipò Àarẹ láifi ti iná ọmọ rara tó bá àwọn ẹ̀rọ asayẹ̀wò cárdi oludìbò kan jẹ. Alága àjọ INEC, ọ̀jọ̀gbọ́n Mahmood Yakubu, sọ èyí di mímọ̀ nígbà tó sèfilọ́lẹ̀ ibùdó kan táwọn ẹgbẹ́ ajàfẹ́tọ ọmọnìyàn yóò ti máà tọpinpin ètò ìdìbò. Ọga […]Continue Reading