Home Archive by category Yoruba (Page 32)

Yoruba

Yoruba

Sanwoolu sàbẹ̀wò àìròtì sílé ẹ̀kọ́ girama kékeré nílu èkó

Gómìnà Babajide Sanwoolu ti ìpínlẹ̀ Èkó ti tẹnumọ́ ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ nínú isẹ́ àgbẹ̀ ìgbàlódé. Gómìnà Sanwoolu sọ èyí di mímọ̀ nígbàtí ó ńkọ́ àwọn akẹ́kọ nípele ẹ̀kọ́ girama kékeré kejì àti ìkẹ́ta nílé ẹ̀kọ́ girama Oregun lágbègbè Ìkẹjà nílu Èkó. Ọgbẹni Sanwoolu ló sàbẹ̀wò àiròtẹ́lẹ̀ sílé ẹ̀kọ́ náà Continue Reading
Yoruba

Asòfin fi ara rẹ̀ jìn láti máà kọ́mọ níyàrá ìkàwé

Akójanu ilé ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ Ọsun, ọ̀gbẹ́ni Tunde Ọlatunji ti yọ̀nda ara rẹ̀, láti máà kọ́ àwọn ọmọ ilé-ẹ̀kọ́ ní ẹ̀kọ́ ìsirò àti ẹ̀kọ́ nípa ìbásepọ̀ ẹ̀dá, ojúse àtẹ̀tọ́ aráalu tamọ̀sí, Civic Ẹducation láwọn ilé-ẹ̀kọ́ tó wà lẹ́kùn ìdìbò rẹ̀. Ọgbẹni Ọlatunji ló sọ̀rọ̀ yíì lákokò tó ń báwọn akẹ́kọ àtàwọn olùkọ́ sọ̀rọ̀ lórí èróngbà […]Continue Reading
Yoruba

Àjọ ìsọ̀kan àgbáyé ti dába owó orí láti gbógunti ìsòro àirílégbé nílẹ̀ yí

Níbàyíná, asojú pàtàkìlájọ ìsọ̀kan àgbáyé arábìnrin Leilana Fartha, ti rọ ìjọba àpapọ̀ láti máà gbé gẹ́gẹ́ owó orí sísan láwọn ilégbe ìjọba tíkò sáwọn èèyàn níbẹ̀ lọ́nà àti fi wójùtú sọ́kanòjòkan ìsòro àinílélórí tó ńkojú àwọn èèyàn ilẹ̀ Nàijírìa. Arábìnrin Fartha ló fìdí èyí múlẹ̀ nílu Abuja, tó sì fàidunú rẹ̀ hàn lórí àwọn ìpèníjà […]Continue Reading
Yoruba

Àjọ EFCC, àti ilé ẹ̀kọ́ gíga fọwọ́sowọ́pọ̀ láti gbogúnti ìwà ìbàjẹ́

Olùdarí àjọ tó ń gbógun ti síse owó ìlú kúmọkùnọ nílẹ̀ yí EFCC, ẹ̀ka ti gúúsù ìwọ̀orùn ilẹ̀yí, ọ̀gbẹ́ni Friday Ebelo ti tọ́ka sí wíwa ọlà òjijì gẹ́gkbí oun tó ńse okùnfà bí àwọn ọ̀dọ́  Se ńlọ́wọ́ sí ìwà jìbìtì àti àwọn ìwà ìbàjẹ́ min tó fara pẹ́ẹ̀. Ọgbẹni Ebelo sọ̀rọ̀ yí di mímọ̀ nígbàtí […]Continue Reading
Yoruba

Iléésẹ́ ológun júwe ilé fáwọn òsìsẹ́ taje ìwà ìbàjẹ́ si mọ́ lórí

Ilẹ́ẹ́sẹ́ ológun orílẹ̀èdè yi sọ pé, òun ti gbasẹ́ lọ́wọ́ àwọn sọ́jà mẹ́ta kan tí wan wà lára àwọn ọmọ ikọ̀ ajínigbé, tọ́wọ́ báà, lẹ́yìn odi ìlú Maiduguri. Ọgaologun fún ikọ̀ Lafiya Dole, ọ̀gágun Olusẹgun Adeniyi ló kéde ọ̀rọ̀ yí, nígbàtí ń fáà àwọn ọlọ́pa lọ́wọ́ nílu Maiduguri. Ọgagun Adeniyi sọ pé, nínu ilé kan […]Continue Reading
Yoruba

Ìpínlẹ̀ Ògùn bojúwò ìbéére lórí àgbékalẹ̀ ilé ẹ̀kọ́ fásitì

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ògún sọ pé, òhun ti ń bojúwò ìbéére àwọn èèyàn ẹkùn ìdìbò àrigbùgbù àti ìwọ̀orùn ìpínlẹ̀ Ògùn, tó wọ́n ní àwọn na ń fẹ́ kí iléékọ gíga fásitì wà ní agbègbè àwọn. Gómìnà ìpínlẹ̀ Ògùn, Dapọ Abiọdun ló kéde ọ̀rọ̀ yi nílu Abẹokuta, níbi tó ti sàlàyé fún àwọn asojú ẹkùn dìbò méjèjì […]Continue Reading
Yoruba

Òjísẹ́ Ọlọ́run gba ìmọ̀ràn lórí ìfọkànsì

Bísọ̀bù ìjọ Victory International Church, nílu ìbàdàn, Àlúfà Taiwo Adelakun ti gba ọmọlẹ́yìn Kristi níyànjú láti jẹ́ olùgbọ́ràn, kí wọ́n se fi tọkàntara se isẹ́ Ọlọ́run, kí wọ́n ba lè gbádùn oore-ọ̀fẹ́ rẹ̀. Bisọbu Adelakun sọ̀rọ̀ ní níbi ìpàgọ̀ òjọ̀dún ìjọ His Pavilion Christian Centre, tó wà ní Àkóbọ̀ nílu Ìbàdàn. Bisọbu na sàpèjúwe oore-ọ̀fẹ́ […]Continue Reading
Yoruba

Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọyọ ní káwọn èèyàn ó dẹ́kun ìwà tólèfa ẹ̀kún omi

Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọyọ ti rawọ́ ẹ̀bẹ̀ sáwọn olùgbé láwọn agbègbè tí ẹ̀kún omin ti ńsọsẹ́, láti kúrò níbẹ̀ náà láti dènà lílúgbàdì ẹ̀kún omi, bí ìjọba se ńgbé ìgbésẹ̀ láti pinwọ́ ẹ̀kún omi láwọn agbègbè náà. Alákoso fọ́rọ̀ àyíká àtàwọn ohun àlùmọ́nì, ọ̀gbẹ́ni Kẹhinde Ayọọla, sọ èyí lásìkò tó sàbẹ̀wò sáwọn agbègbè kan tẹ́kun omin […]Continue Reading
Yoruba

Àarẹ Buhari késí ilẹ̀ òkèrè láti dọwọ́pọ̀ pẹ̀lú ilẹ̀ Nàijírìa

Àarẹ Muhammadu Buhari ti rọ àwọn olùdóokowò láti orílẹ̀dè Germeny pé kíwọ́n wá gbé ilésẹ́ ajé kalẹ̀ papáà lẹ́ka ohun àmúságbara. Nígbà tó ńgba ìwé ìwosẹ́ látọ̀dọ̀ asojú ilẹ̀ Germany sórílẹ̀èdè Nàijírìa Birgitt Ory, nílé àarẹ Buhari fọwọ́ ìdánilójú sọ̀yà fáwọn oní ilésẹ́ ajé láti orílẹ̀èdè Germany, pé ìjọba yóò buọlá fún àdéhùn gbogbo. Ìwé […]Continue Reading
Yoruba

Ìgbìmọ̀ àpapọ̀ Gómìnà sọ àsọyán lórí owóya

Ìgbìmọ̀ àwọn Gómìnà nílẹ̀ Nàijírìa, NGF, sọpé àwọn ńse àtòpọ̀ àkọlé ètò ìsúnná wọn lọ́wọ́, káwọn tó lèè mọ̀ báwọn yóò se ìdápadà owó ìyọnilọ́fìn tíjọba àpapọ̀ fún wọn. Alága ìgbìmọ̀ ọ̀hún títún se Gómìnà ìpínlẹ̀ Èkìtì, ọ̀mswé Kayọde Fayẹmi, ẹnitó sọ̀rs yíì lkyìn ìpàdé alátìlẹ̀kùn mọ́rí se kan nílu Abuja. Ó sàlàyé pé, àwọn […]Continue Reading
Yoruba

Ìjọba ìpínlẹ̀ Òndó fi ìrètí hàn láti pinwọ́ ìarísẹ́se

Gómìnà ìpínẹ̀ Òndó, ọ̀gbẹ́ni Rotimi Akeredolu ti sọ́ di mímọ̀ pe ètò ìsèjọba òhun yóò fojúsùn ètò ọ̀gbìn gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà kan gbogi láti wójùtú sí àinísẹ́ lọ́wọ́ àwọn ọ̀dọ́ nípinlẹ̀ náà. Gómìnà Akeredolu sọ èyí níbi ìfilalẹ̀ ìwé kan nípinlẹ̀ Èkó. Ó sàlàyé pé, àinísẹ́ lọ́wọ́ jẹ́ ìpèníjà kan gbogi tó ńkojú àwọn ọ̀dọ́ […]Continue Reading
Yoruba

Ìpínlẹ̀ Ọyọ sètò àpérò lórí owóna àti ìgbanisísẹ́

Àwọn asòfin ní ilé ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ Ọyọ ńsètò ìpàdé ọlọ́jọ́ mẹ́rin lọ́wọ́ báyi lórí àbá òfin mẹ́ta kan tó sepàtàkì. Àwọn àbá òfin ọ̀hún ni, àbà tóníse pẹ̀lú àgbéga àjọ tó ń dá isẹ́ ajé sílẹ̀ ọdún 2019, àbá tí níse pẹ̀lú àjọ tó ńgbóguntí ìwà àbàjẹ́ tófimọ́ àbá tóníse pẹ̀lú àtúntò àti ìdúró […]Continue Reading
Yoruba

Erédi ta fíwó àwọn ilé ìtàjà lágbègbè alagbaka – Ìjọba Òndó

Ọpọ ilé ìtajà lójú òpópónà alagbaka Àkúrẹ́, nípinlẹ̀ Òndó, ti jẹ́ wíwólulẹ̀ látọwọ́ àwọn òsìsẹ́ ilésẹ́ tó ńrísí àtò gbogbo àti ìdàgbàsókè ìlú ńlá ńlá Àwọn tóni àwọn ilé ìtàjà ọ̀hún déba tótijẹ́ wíwólulẹ̀ lóru mọ́jú. Akọròyìn ilésẹ́ wa tó sàbẹ̀wò sí ibi ìsẹ̀lẹ̀ náà jábọ̀ pe, ilé-ìtàjà asọ, ibùdó ìtura àti ibùdó tí wọ́n […]Continue Reading
Yoruba

Ilé asòfin ní kí ọ̀gá Bánki àpapọ̀ farahàn lórí àkànse isẹ́

Ìgbìmọ̀ tẹkótó ilé tó ńrísí idàgbàsókè ẹkùn Niger Dẹlta, NDDC, ti kanpá fún ọ̀gá àgbà bánki àpapọ̀ ilẹ̀ yíì Godwin Emefiele láti farahàn níwájú ilé. Alága, ìgbìmọ̀ ọ̀hún, ọ̀gbẹ́ni Nicholas Ossai, sọ fáwọn oníròyìn nílu Abuja, wípé àwọn ti gba àkọsílẹ̀ láti ilésẹ́ bánki àpapọ̀ lórí àwọn isẹ́ àkànse lẹ́kùn Niger Delta tótijẹ́ pípatì . […]Continue Reading
Yoruba

Ìjọba àpapọ̀ gbé ìgbésẹ̀ lórí iná ọba

Adarí ilé ìgbìmọ̀ asojú sùfin, ọ̀gbẹ́ni Fẹmi Gbajabiamila ti sọpé ilé yóò ripé àwọn èèyàn ilẹ̀ yíì gbádùn owó tí wọ́n ńsan fún iná ọba, tí wọ́n kòsì ní fàyègba owó iná-ọba tó ńwọ àwọn aráàlu lọ́ọ̀rùn. Adarí ilé sàlàyé pé, ilé yóò mọ́mọ̀ jíròrò lẹ́kunrẹ́rẹ́ lórí owó gọbọi táwọn ilésẹ́ apinnáká ma ń bù […]Continue Reading
Yoruba

Òsìsẹ́ ibùdó ìgbafẹ́ ìlú Ọyọ gba àmì ẹ̀yẹ o pegedé

Ibùdóìgbafẹ́ ìjọba àpapọ̀ tó wà nílu Ọyọ, ni wọ́n ti fi àmìn ẹ̀yẹ dá àwọn òsìsẹ́ tó sẹ̀sẹ̀ gba àgbéga lẹ́nu isẹ́ lọ́lá èyí tó yàtọ̀ gédégbé sí báwọn òsìsẹ́ kan séngba ìwé àgbéga tẹ́lẹ̀rí tí wọ́n yo sì fipamọ́. Akọ̀ròrìn ilésẹ́ Radio Nigeria fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pe, ìgbésẹ̀ tuntun yi lówà níbamu pẹ̀lú bí […]Continue Reading
Yoruba

Àwọn obìnrin fẹ̀húnú hàn lórí ìsekúpani nílé ìtura

Ogunlọ́gọ̀ àwọn obìnrin ni wọ́n yan bí ológun lọ sílé ìjọba nílu Port-Harcourt láti lọ fi ẹ̀húnú hàn lórí ìsekupa àwọn ọ̀dọ́bìnrin ní àwọn ilé ìtura ọ̀tọ̀tọ̀ n’ípinlẹ̀ Rivers. Àwọn obìnrin shún ni wọ́n wọ asọ dúdú, tí wọ́n sìn késí ìjọba láti gbé ìgbésẹ̀ burúkú náà. Wọ́n tọ́kasi wípé gbogbo èyàn pátápátá lái yọ […]Continue Reading
Yoruba

Ọwọ́ sìnkú òfin tẹ ọkùnrin kan ńpinlẹ̀ Ọsun lórí ìwé ìrìnnà òfegè

Ọkùnrin kan Joseph Johnson ẹni ọdún mẹ́tàlélógún ni ónkáwọ́pọ̀n sẹ́yìn níwájú ilé ẹjọ́ magisrate nípinlẹ̀ Ọsun, nílu Osogbo, láti sàlàyé on tórí labẹ̀ tó fi garu ọwọ́, lórí kíkùnà láti gba ìwé ìrìnà sílẹ̀ Canada fún oníbarà rẹ̀. Arákùnrin yi, ni ìròyìn fìdí ẹ̀ múlẹ̀ pe ó gba ẹgbẹ̀rún lọ́nà ẹdẹgbẹrin naira lọ́wọ́ Bukọla Alayande, […]Continue Reading
Yoruba

Alákoso pè fún àjọsepọ̀ tó lóórin láàrin àwọn iléésẹ́

Alákoso kejì fọ́rọ̀ ilẹ̀ òkèrè Ambassador Zubairu Dada, ti pè fún ìbásepọ̀ tó gbúmọ̀ láarin gbogbo àwọn lájọ-lájọ àti ẹ̀ka tó wà lábẹ́ ìsàkóso ọ̀rọ̀ nípa ilẹ̀ òkèrè. Ó sọ̀rọ̀ yí nílu Abuja, lásìkò tón gba àwọn ìgbìmọ̀ aláse ẹ̀ka àtò gbogbo nílẹ̀ adúláwọ̀ lálejò ní ófìsì rẹ̀. Alákoso kejì fọ́rọ̀ ilẹ̀ òkèrè, Ambassador Dada […]Continue Reading
Yoruba

Ìpínlẹ̀ Ọyọ gbé ìgbésẹ̀ lórí ilégbe ìrọ̀rùn

Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọyọ ti kéde ìpinu rẹ̀ láti ta àwọn ilégbe méjìdínlógójì tówà ní “Calton-Gate Estate” Àkóbọ̀ ìbàdàn fáwọn  arálu lówó tí o gajura lọ. Alákoso fọ́rọ̀ ilẹ̀ ilégbe àti ìdàgbàsókè ẹsẹ̀kùkú, ọ̀gbẹ́ni Abiọdun Abdu-Raheem ló jẹ́ kọ́rọ̀ yi di mímọ̀ lásìkò tón se àbẹ̀wò sáwọn ilégbe tó jẹ́ tìjọba nílu’bàdàn. Ọgbẹni Abdulraheem sọ pé, […]Continue Reading
Yoruba

Iléesẹ́ ọlọ́pa sèlérí àabò tó gbópọn fún àwọn èèyàn òkè Ògùn

Alákoso fún ilésẹ́ ọlapa nípinlẹ̀ Ọyọ, ọ̀gbẹ́ni Shina Olukọlu ti sèlérí fáwọn èyàn Òkè-Ògùn pé ètò àbò tó múnádóko yó wà fún ẹ̀mí àti dúkia àwọn èyàn agbègbè náà. Ọgbẹni Olukolu ló sèlérí yi nílu Saki, lásìkò tó sàbẹ̀wò ẹnusẹ́ ságbègbè náà, tó sì késí àwọn olùgbé láti jẹ́ kámugbòrò bá ìbásepọ̀ lálafìa. Bẹ́ẹ̀ lótún […]Continue Reading
Yoruba

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọyọ gbé ìgbésẹ̀ lórí àwọn ilé ìwé alákọbẹ̀rẹ̀

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ọyọ sọpé, òun kòní yíì ìpinu òhun padà láti gbé àwọn ilé ìwé alákọbẹ̀rẹ̀ aládani tí o kójú òsùwọ̀n tàbí àwọn tójẹ́ gbígbékalẹ̀ láibofinmu tìpa. Alága àjọ Subẹb nípinlẹ̀ Ọyọ, ọ̀mọ̀wé Nureni Adeniran sọ̀rọ̀ yíì di mímọ̀ nígbà tó ńbá àwọn oníròyìn sọ̀rọ̀ nílu Ìbàdàn. Ó sàlàyé pé ìgbésẹ̀ náà sepàtàkì nítorí báwọn […]Continue Reading
Yoruba

Ilé asòfin ìpínlẹ̀ Ọyọ se àgbékalẹ̀ ìgbìmọ̀ tẹkótó

Adarí ilé ìgbìmọ̀ asòfin ìpínlẹ̀ Ọyọ, ọ̀gbẹ́ni Debọ Ogundoyin ti gba alága àtàwọn ìgbìmọ̀ tẹkótó ilé ẹlẹ́ni márùndínlọ́gbọ̀n níyànjú láti sisẹ́ wọn bí isẹ́. Adarí ilé gbé àmọ̀ràn yíì kall lákokò tó ńbura fún ìgbìmọ̀ náà níbi ètò kan èyí tí pínpín ìwé òfin àtẹ̀lée fáwọn ìgbìmọ̀ ọ̀hún tí wáyé níbẹ̀ pẹ̀lú. Ó sàlàyé pé […]Continue Reading