Home Archive by category Yoruba (Page 31)

Yoruba

Yoruba

Ìjọba àpapọ̀ mú ìdàgbàsókè bá ẹ̀ka ìrìn àjò afẹ́

Alákoso farọ̀ ìròyìn àti àsà lórílẹ̀dè yi, Àlhájì Lai Muhamed, sọ pé láipẹ ni ìjọba àpapọ̀ yó fi ètò kan lọ́lẹ̀ lórí ọ̀rọ̀ àsà àti ètò ìrìnàjò afẹ́. Àlhájì Mohamed sọ pé, ìjọba ní ìpinnu láti jẹ́ kí orílẹ̀èdè yi jẹ́ ibi tí àwọn arìnrìnàjò afẹ́ yo máà nífẹ àti wá sàbẹ̀wò si. Alákoso fọ́rọ̀ […]Continue Reading
Yoruba

Ìjọba àpapọ̀ ti ọ̀mọ̀wé Adesina lẹ́hin láti díje fún pò Bánki Adúláwọ̀

Ìjọba àpapọ̀ fún alákoso fétò ọ̀gbìn tẹ́lẹ̀rí lásẹ láti díje fún pò Bánki adúláwọ̀ Àarẹ Muhammadu Buhari tiya ọ̀mọ̀wé Akinwumi Adesina pé kó tún díje fún ipò alákoso àjọ bánki ill Africa tó ń bójútó ọ̀rọ̀ ìdàgbàsókè Africa. Ọmọwe Akinwumi fún ráà rẹ̀ ló kéde ọ̀rs yi níbi àpéjọpọ̀ kan nílu Èkó. Ọmọwe Akinwumi tó […]Continue Reading
Yoruba

Ilẹ̀ South Africa tọrọ àforíjìn lọ́wọ́ ilẹ̀ Nàijírìa

Àarẹ ilẹ̀ South Africa, Cyril Ramaphosa ti tọrọ àforíjìn lórí ìkọlù àwọn ọmọ ilẹ̀ Nàijírìa tó ńgbé ní South Africa. Eléyi wáyé níbi ìjókosọ̀rọ̀pọ̀ pẹ̀lú àarẹ ilẹ̀ Nàijírìa Mohammadu Buhari nílu Pretoria. Àarẹ Buhari wá rọ ilẹ̀ South Africa láti sètò àabò tó nípọn yíká àwọn iléésẹ́ ńlá ńlá tó jẹ́ tọmọ ilẹ̀ òkèèrè paapa […]Continue Reading
Yoruba

Ẹsan owó osù tuntun fún gbogbo òsìsẹ́ – Ẹgbẹ́ òsìsẹ́

Ẹgbẹ́ òsìsẹ́ lápapọ̀ ilẹ̀ yíì, NLC, áti TUC, sọ pé, àwọn kò le sọ ìgbà tàbí àkókò táwọn òsìsẹ́ filè se àfaradà suuru bí ìjọba àpapọ̀ bá kọ̀ láti sàmúlò owó osù tuntun àwọn òsìsẹ́ tó kéré jùlọ títí ọjọ́ kẹrìndílógún osù yíì. Wọ́n ní gbogbo bí mímú àtúnse dé bá ìlànà sísan owó náà […]Continue Reading
Yoruba

PDP tako dídá àwọn ẹnu ìloro ojú òpópónà márosẹ̀ padà

ẹgbẹ́ òsèlú PDP ti lóun kò faramọ́ èròngbà àarẹ Muhammadu Buhari láti dá àwọn ẹnu ìloro tó wọ àwọn ojú òpópónà márosẹ̀ ile yíì padà. Nínú àtẹ̀jáde kan tíwọ́n fi síta fáwọn oníròyìn nílu Abuja lèyí ti jẹyọ, látọ̀dọ̀ akọ̀wé àgbà fétò ìròyìn ẹgbẹ́ òsèlú PDP, ọ̀gbẹ́ni Kọla Ọlọgbọndiyan, ẹgbẹ́ òsèlú náà wá kọminú pé, […]Continue Reading
Yoruba

Ìtàn ìlú Ọtan-Ayegbaju

Ọtan Ayegbaju tó jẹ́ ibùjóko ìjọba ìbílẹ̀ Boluwaduro nípinlẹ̀ Ọsun ló kalẹ̀ sí apá àríwá ní ẹkùn Ìwó-Orùn gúsù tó sì fi Kìlómétà mẹ́tàdínlógójì jìnà sí ìlú Osogbo. Nínú àkànse ìròyín yi, oníròyìn wa, Wasiu Ajadosu sàgbéyẹ̀wò oun tó wà lẹ́yìn orúkọ ìlú ìsẹ̀nbáyé náà. Àtúpalẹ̀ rẹ̀ réè láti ẹnu  Serah Sanni Otan Ayegbaju to […]Continue Reading
Yoruba

Onímọ̀ bèèrè fún ìkọ́sẹ́mọsẹ́ nídi ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́

Wọ́n ti gbàwọn tóngbóhùn sáfẹ́fẹ́ látorí ẹ̀rọ ayélujára àtàwọn olùdásílẹ̀ rẹ̀ níyànjú láti jẹ́ akọ́sẹ́mọsẹ́ nídi isẹ́ tíwọ́n yàn láayo. Alájutó àgbà ilé-isẹ́ ẹlẹ́rọ amìnlújìnjìn Premier tó wà nílu ìbàdàn, Ẹniọ̀wọ̀ Niyi Dahunsi ló gbọ̀rọ̀ àmọ̀ràn yíì kalẹ̀, lákokò tó ń gbéwe àpilẹ̀kọ kan kalẹ̀ níbi ayẹyẹ àkọ́kọ́ ilé-isẹ́ Radio orí ẹ̀rọ ayélujára, Maranatha. Ẹniọ̀wọ̀ […]Continue Reading
Yoruba

Gómìnà Sanwoolu gbàmọ̀ràn lórí ìfọkànsì

Gómìnà Babajide Sanwo-Olu gbàwọn ọmọ orílẹ̀dè yíì níyànjú láti nígbàgbọ́ kíwọ́n sì fìmọ̀sọkan, pé ilẹ̀ yíì sì máà dára. Gómìnà Sanwo-Olu tún kọminú lórí báwọn ọmọ orílẹ̀dè yíì kan se ńsíkúrò nílẹ̀ yíì, lọ sí ilẹ̀ òkèrè níbi tílẹ̀ tó ń mú kílẹ̀ Nàijírìa pàdánù àwọn ọlọ́pọlọ pípé ẹ̀dá, tíwọ́n lè mú ìdàgbàsókò bá orílẹ̀dè. […]Continue Reading
Yoruba

Iléésẹ́ ológun fọkàn aráalu balẹ̀ lórí ìbọn yínyìn láyajọ́ ọjọ́ òmìnira

Ilé isẹ́ ọmọ ológun orílẹ̀dè yíì, ti ké sáwọn aráalu láti máà se fòyà rárá lórí ìgbésẹ̀ ìbọn yínyìn tí yóò wáyé lákokò ayẹyẹ àyájọ́ òmìnira ilẹ̀ fún tọdún 2019 tawàyí. Èyí ló jẹyọ nínú àtẹ̀jáde kan tígbákejì olùdarí agbẹnusọ fún ilé-isẹ́ ológun náà, ọ̀gágun Haruna Tagwai fisíta nílu Abuja. Ọgagun náà tó tọ́kasi pé, […]Continue Reading
Yoruba

Àarẹ Buhari pè fún ìgbélárúgẹ àsà àti isẹ́

Àarẹ orílẹ̀dè yíì Muhammadu Buhari ti ké sáwọn ọmọ ilẹ̀ Nàijírìa láti máà dábòbò kíwọ́ sì máà mú àgbéga bá àsà àti isẹ́ ilẹ̀ yíì, pẹ̀lú àtọ́kasípé, látara àsà àti ìse àwọn èèyàn niwọ́n fi máà ń mọ bí ti irúfẹ́ ẹni bẹ́ẹ̀ tiwà. Lákokò ayẹyẹ ọlọ́jọ́ fún tọdún 2019 tó wáyé láafin Ọọni tìlú […]Continue Reading
Yoruba

Ìjọba àpapọ̀ fọwọ́sí owóna àkànse isẹ́ ọ̀nà

Ìgbìms alásẹ ìjọba àpapọ̀ ti fọwọ́sí billiọnu lanà ọgafà náirà ọdún kan, fún isk àkàse àwọn ojú ọ̀nà oníbejì látìlú Ìbàdàn, sí Ìlésà, Ifẹ̀, tófimọ́ Kano títídé Kastina. Alakoso fọ́rọ̀ isẹ́ àti ilégbe nílẹ̀ yíì, ọ̀gbẹ́ni Babatunde Fashọla, tó sísọ lójú ọ̀rs yíì nílu Abuja, sọpé, bí ọgọ́rin biliọnu náirà odúkan látara owó náà ni […]Continue Reading
Yoruba

Àjọ NBC gbé ìjìyà kalẹ̀ fún àwọn iléésẹ́ ìròyìn márùndínláadọfa

Àjọ tó ńrísọ́rọ̀ isẹ́ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ NBC, ti gbé ìjìyà kalẹ̀ fáwọn ilé-isẹ́ ìgbóhùnsáfẹ́fẹ́ bí márùndínláadọta lórí ẹ̀sùn títàpà sófin àjọ náà láarin osù mkfà àkọ́kọ́ nínú ọdún yíì. Olùdarí àgbà àjọ NBC, ọ̀gbẹ́ni Ishau Kawu tó sísọ lójú ọ̀rọ̀ yíì nílu Abuja, mẹ́duba diẹ lára àwọn ẹ̀sùn náà, bí síwọn àwọn ọ̀rs kòbákùngbé, ọ̀rs ebu, […]Continue Reading
Yoruba

Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọyọ laago ìkìlọ̀ fáwọn tó kọ́lé lái gbàsẹ

Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọyọ ti késí àwọn tóní ilẹ̀ ní ìpínlẹ̀ Ọyọ, láti lọ gba gbogbo ìwé àsẹ tóyẹ kí ilé wọn mábadi gbígbẹ̀sẹ̀lé tàbí wíwó irúfẹ́ ilé náà. Alákoso fọ́rọ̀ ilẹ̀ ilégbe àti ìdàgbàsókè àwọn ìlú ńlá-ńlá, ọ̀gbẹ́ni Abiọdun Abdu-Raheem sọ èyí lákokò tó sàbẹ̀wò sáwọn ibùdó tójẹ́ tìjọba nílu ìbàdàn, pẹ̀lú àlàyé pé, ìjọba […]Continue Reading
Yoruba

Àarẹ Buhari bèèrè fún ìdápadà àwọn dúkia tí àwọn kan kósálọ

Àarẹ Muhammadu Buhari ti bèrè fún ìsọ̀kan lárin àwọn orílẹ̀dè ilẹ̀ adúláwọ̀, lọ́nà àti lè lánfàní àtigba àwọn dúkia wọn tí ótijẹ́ jíjíkólọ sórílẹ̀ẹ̀dè ibòmíràn padà. Àrẹ sọ yíì níbi ètò kan tójẹ́ gbígbékalẹ̀ lórí síse ètò ìsúná lọ́nà àitọ́, níbi IFFS, ìpàdé ilé ìgbìmọ̀ asòfin àjọ ìsọ̀kan àgbáyé tó ńlọ lọ́wọ́ ní New York […]Continue Reading
Yoruba

Ìpínlẹ̀ Èkìtì bèèrè fún ìfowósowọ́pọ̀ lórí ọ̀rọ̀ ẹ̀kọ́

Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkìtì ti rọ àwọn ọmọbíbí ìpínlẹ̀ náà láti dásí ìgbésẹ̀ àtúntò ẹ̀ka ètò ẹ̀kọ́ tó ńlọ lọ́wọ́ nípinlẹ̀ náà. Igbákejì Gómìnà, Ọtunba Bisi Ẹgbẹyẹmi sọ̀rọ̀ yíì nígbà tó ńsàgbékalẹ̀ ìwé kíkà tóótó irinwó àtàwọn ohun èlò ìkẹ́kọ min-in, fún lílò àwọn akẹ́kọ lágbègbè Ìgbèmọ̀- Èkìtì. Ọtunba Ẹgbẹyẹmi wá fikun pé, ìjọba yóò fàyègba, […]Continue Reading
Yoruba

Auto Draft

Àjọ olùlanilọ́yẹ̀ aráálu sojúse ẹni, NOA, ti sàlàyé ìdí tó fi sepàtàkì kájọsepọ̀ tó dán mọ́ràn wà láarin àwọn ọmọ orílẹ̀dè yíì láifi tẹ̀sìn, tẹ̀yà tàbí èyíkèyí ẹgbẹ́ òsèlú kankan se, fálafìa orílẹ̀dè yíì. Nígbà tó ń sọ̀rọ̀ níbi ètò ìlanilọ́yẹ̀ kan tó wáyé nílu Ìbàdàn èyí tó ń sàmì àyájọ́ àláfìa fún tọdún yíì, […]Continue Reading
Yoruba

Ilé Asòfin Sèlérí Ibuwọ́lù Ofin ẹ̀ka Epo Rọ̀bìi.

Àarẹ ilé ìgbìmọ̀ asòfin àgbà, Ahmed Lawan, sọ pé, ilé asòfin náà yóò buwọ́lu àbá òfin tóníse pẹ̀lú ilé-isẹ́ epo bẹntiro, PIB, kó tó dìparí ọdún 2020. Nínú ọ̀rọ̀ àkọ́sọrẹ̀ lákokò tó ń sèfilọ́lẹ̀ àadọ́rin ìgbìmọ̀ tẹ̀kótó ilé asòfin àgbà níbi ìjóko ilé tó wáyé nílu Abuja ni asòfin Lawan ti fìdí èyí múlẹ̀. Ó […]Continue Reading
Yoruba

Àjọ JAMB gbé ìgbésẹ̀ láti dénà màgòmágó ìdánwò

Àjó tó ń rí sétò ìdánwò ìgbaniwọ́ló sáwọn ilé ẹ̀kọ́ gíga Jamb ti ké sáwọn akẹ́kọ tí yóò jóko se ìdánwò UTME, tọdún 2020, láti lọ gba núnber ìdámọ̀ ọmọ ilẹ̀ yíì. Agbẹnusọ fájọ ọ̀hún, ọ̀mọ̀wé Fabian Benjamin sọ pé, èròngbà ìgbésẹ̀ náà ni latirí dájú pé, gbogbo àwọn àkọsílẹ̀ tóyẹ nípa àwọn akẹ́kọ náà […]Continue Reading
Yoruba

Gomina Makinde yan Ọ̀mọ̀wé Babatunde ni Olùbádámọ̀ràn Fétò Ọrọ́ Ajé

Gómìnà ìpínlẹ̀ Ọyọ, onímọ̀ ẹ̀rọ Seyi Makinde ti fọwọ́sí ìyànsípò onímọ̀ nípa ètò ọ̀rọ̀ kan látẹ̀ka tíwọ́n ti ńkọ́ nípa ìmọ̀ nípa ọrọ̀ ajé nílé ẹ̀kọ́ gíga fásitì Ìbàdàn, ọ̀mọ̀wé Musibau Babatunde gẹ́gẹ́bí olùbádámọ̀ràn pàtàkì rẹ̀ fétò ọrọ́ ajé. Àtẹ̀jáde kan tákọ̀wé àgbà sígómìnà fétò ìròyìn, ọ̀gbẹ́ni Adisa fisita só pé, ìyannisípò ọ̀mọ̀wé Babatunde náà […]Continue Reading